Yoruba

Arabic (in Transliteration)

Meaning in English

Ààrá

Ar-Racad

Thunder

Abẹrẹ

Ibrah

Needle

Àduà

Ad-Duca

Prayer

Alááfià

Al-cĀfiyah

Good Health

Alààyè

Al-Ḥayyu

The Living One

Àléébu

Al-cAyb

Blemish

Àlikámà

Al-Qamhu

Wheat

Àlubarika

Al- Barakah

Blessing

Àlùbọsà

Al-Baṣal

Onion

Àluwàlá

Al-Wuḍu

Ablution

Àṣálẹ

Āsal

Evening

Baálé/Baálẹ

Bacal

Husband/ Lord

Dábirà

Dabbara

To dispose

Èébú

cAyb

Abuse

Fáàrí

Fakhr

Ostentation

Fìtílà

Fatilah

Wick

Hàntu/Hànturu

Khaṭṭu

To write Arabic character

Iṣẹlẹ

Ḥasala

To happen

Ileyá

Adhā

Immolation

Máléékà

Malaika

Angel

Òmùgọ

Ḥamuqa

Stupid/Imbecile

Ọdún

Icd

Festival

Wákàtí

Waqt

Time/Hour

Iná

An-Nār

Fire

Ọlọhun

Allah

God