S/No.

Newly coined words in Yorùbá language

Meaning in English language

1.

Amúnisìn

Oppressor

2.

Ìdánásunlé

Arson

3.

Katakata

Caterpillar

4.

Adúnkookò-mọ́ni

Terrorist

5.

Alúpúpú/Tatapùpù

Motorcycle

6.

Àgùnbanirọ̀

Youth corper

7.

Ìgbẹ́-gbuuru

Diarrhoiea

8.

Onígbáméjì

Cholera

9.

Apẹ̀tùsááwọ̀

Anti-riot police

10.

Akọ́nimọ̀ọ́gbá

Coach (Football)

12.

Mọ̀nàmọ́ná

Electricity

13.

Súnkẹrẹgbàkẹrẹ

Go-slow

14.

Fìdí-hẹẹ́

Interim

15.

Àpérò

Conference

16.

Kólẹ̀-kódọ̀tí

Waste management board

17.

Gbálé-gbáta

Environmental sanitation

18.

Ayédèrú

Fake

19.

Ìkànnì

Channel

20.

Ìpolongo

Campaign