S/No.

Newly coined words in Yorùbá language

Meaning in English language

1.

Òdo-méjì-tógbé-ẹẹ́jọ sáàrin

080...GSM initial codes

2.

Aṣọ-májámájá-ẹgbẹ́jọdá-àwọn-ọlọ́kadà

Reflexive jackets of the motorcyclist

3.

Owó-sábáńmu-òun-rèé

Bribery

4.

Àwọn-àsẹ̀sẹ̀-jáde-ilé-ìwé-gíga

Fresh graduates

5.

Lẹ́tà-iṣẹ́-ìlú-yá/ìwe-ìsìnrú-ìlú-yá

Call-up letter (for Youth Service)

6.

Ẹ̀rọ-móhùnmáwòrán-abálédọ́gba

LCD/Plasma television

7.

Ọkọ̀-òfurufú-agbérapá

Helicopter

8.

Ẹ̀rọ-ayára-bí-àṣá-àgbélétan

Laptop

9.

Akẹ́kọ̀ó-ìdàbọ̀

Part-time student

10.

Akẹ́kọ̀ó-ìgbàyíláárọ́

Sandwich student

12.

Abẹ́rẹ́-kára-ó-le

Vaccine

13.

Àrun-fòníkú-fọ̀la-ǹ-de

Sickle cell disease

14.

Ilé-ìgbìmọ̀-aṣojú-ṣòfin

House of Representatives

15.

Ọkọ̀-gbókùú-gbáláàrẹ̀

Ambulance

16.

Eré-à-sá-gbọ̀n-rìrì

Marathon race

17.

Ìdájọ́-ikú-lère-ẹ̀ṣẹ̀

Death/capital sentence

18.

Ìtàkùn-ayélujára-ojú-rẹ-dà-jẹ́-n-bá-ọ-dọ́rẹ̀

Facebook

19.

Ìyanṣẹ̀-lódì-aláìní-gbèdéke-ọjọ́

Indefinite strike

20.

Ìlànà-tepo-níye-ó-pé-ọ

Downstream deregulation

21.

Ìlàna-níní-owó-láì-fojú-rí i

Cashless policy

22.

Ìbéèrè-èwo-nìdáhùn

Objective question

23.

Bọ́ọ̀lù-wòmí-n-gbá-sí-ọ

Penalty kick

24.

Balógun-ẹgbẹ́-a-gbá-bọ́ọ̀lù

Team captain

25.

Káàdi-jáde-ní-pápá

Red card

26.

Ẹ̀rọ-alágbèká

Handset

27.

Ìwé àtẹ̀jíṣẹ́

Text message

28.

Titi márosẹ

Expressway

29.

Ibùsọ̀ dúró-n-yẹ̀-ọ́-wò

Checking point

30.

Ẹrọ pọwó-pọwó

ATM machine